Bibeli fun awon omode

Awon Itan ti o feran lati inu Bibeli. Li ofe.

Ipinu wa

Iwe Matthew ori kokandinlogun ese kerinla (Matthew 19:14) so wipe “ Ejeki awon omode wa si odo mi, emase dawon lekun, nitori iru won n’ijoba orun”

Bibeli fun awon omode wa lati fi Jesu Kristi han fun awon omode nipa pinpin itan Bibeli alaworan ati awon oniruru ohun elo, pelu lilo komputa agbaye, fonu olowo/PDA, iwe ihinrere pelebe ati iwe kikun omode, li gbogbo ede ti omode leso.

Awon itan Bibeli yi wa fun pinpin fun gbogbo egberun lona egberun billion awon omode lofe kari aiye.

Pe fun leta irohin